Ewi A?ey? Ominira Naijiria - Funmilayo Adesanya-Davies - Livros - Globeedit - 9786200620330 - 2 de março de 2021
Caso a capa e o título não sejam correspondentes, considere o título como correto

Ewi A?ey? Ominira Naijiria

Preço
R$ 190,90
excluindo impostos

Item sob encomenda (no estoque do fornecedor)

Espera-se estar pronto para envio 2 - 8 de out
Receba avisos sobre novos lançamentos de Funmilayo Adesanya-Davies
Adicione à sua lista de desejos do iMusic

Ainda não avaliado

Èyí ni àw?n EWÌ À?EY?RÍ ÒMÌNIRA NÀÍJÍRÍÀ tí mo kó j? pap?? Ó j?? ohùn ìdùnnú fún mí púp?? láti k? ìwé àkój?p?? ewì yìí. A k? ìwé ewì yìí ni àsìkò tí oríl??-èdè Nàíjíríà pé ?g??ta ?dún láti ?e àyàjó? ?j?? ìbí r?? náà; ti wón ?e À?EY?RÍ ÒMÌNIRA ?G?TA ?DÚN ORÍL?? ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ náà. Àw?n ewì j? ohun àbálàye tí ó j? ?m? Yorùbá lógún. Ní ayé àtij?? ní ilè Yorùbá, ò un ni àw?n bàbá-?lá wa máa ? lò fún ìmò?, ìmò?ràn àti ??k??, ?ùgbó?n won kìí k??? síl?? nítorí pé, w?n kò ní ìmò? mò?ó?k?-mò?ó?kà rárá. Orísírísí ewì ni ó wa, orísírísí ??nà ni a sì lè pín ewì sí. Èrò ?kàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkój?p?? ewì yìí. Nàìjíríà (/na??d??r??/) j?? Oríl??-èdè Olómìnira. Ìj?ba Àpap?? il?? Nàìjíríà j?? oríl??-èdè tí ó ní ìj?ba ìpínl?? m??rindínlógójì tó fi m?? Agb??gb?? Olúìlú Ìj?ba Àpap??. Oríl??-èdè Nàìjíríà wà ní apá Iw?? Oòrùn il?? Áfríkà. Oríl??-èdè yí pààlà p??lú oríl??-èdè Benin ní apá ìw?? Oòrùn, ó tún pààlà p??lú oríl??-èdè olómìnira ti Nij?r ní apá àríwá, Chad àti Kam?róòn ní apá ìlà Oòrùn àti Òkun Atlantiki ni apá gúúsù. Abuja ni ó j?? Olú-Ìlú fún oríl??-èdè náà. Bí ó til?? j?? pé Nàìjíríà ní ??yà púp??, àw?n ??yà m??ta ni w??n tóbi jùl?. Àw?n w??nyí ni ??yà Yorùbá, ??ya Ìgbò ati ??yà Hausa.

Mídia Livros     Paperback Book   (Livro de capa flexível e brochura)
Lançado 2 de março de 2021
ISBN13 9786200620330
Editoras Globeedit
Páginas 68
Dimensões 152 × 229 × 4 mm   ·   119 g
Idioma Afrikaans  

Mais por Funmilayo Adesanya-Davies

Mostrar tudo